SS3 Yoruba Past Questions and Answers- Mock (WASSCE). Get complete Yoruba past questions and answers to prepare for upcoming external examination.
Read Also: JSS3 Yoruba Exam Past Questions- MOCK Free Download
SS3 Yoruba Past Questions and Answers: Complete Questions
ÌPÍN A
ÀKÀYÉ
Ká àyo̩kà ìsàlè̩ yìí, kí o sì dáhùn ìbéèrè tí ó tè̩le e.
Ìlú Ò̩là ni O̩láolú n gbé;ibè̩ ló sì bí gbogbo o̩mo̩ rè̩ sí. Gbogbo àwo̩n o̩mo̩ wò̩nyí ló kàwé dáadáa. Àwo̩n tí ó tí ké̩kò̩ó̩ jade ni Tìjání tí ó je̩ ako̩-níwájú-adájó̩. Bó̩lá ni adarí ilé is̩é̩ mádàámidófò kan ní Sò̩be̩. Lo̩ládé sì ní ò̩gá àgbà pátápátá ní ilé-ìwòsàn ìjo̩ba ní Àpà.
Dáramájà, akó̩s̩é̩-igi O̩láolú, ní gííwá ilé okoòwò káràkátà tí ara rè̩ ní Sohó. Rè̩mí tí í s̩e àbígbè̩yìn, nìkan ló kù ní ilé-è̩kó̩ gbogbo-nìs̩e ní Abraka. Dáramájà wòye pé ó ye̩ kí àwo̩n yé̩ bàbá àwo̩n sí fún is̩é̩ takuntakun tí ó s̩e lórí o̩mo̩. Wó̩n fe̩nu kò láti fi aye̩ye̩ o̩jó̩ ìbí yé̩ bàbá sí.
- Oláolú bí o̩mo̩——–(A) Méjì (b)mé̩ta (c) mé̩rin (d) márùn-ún.
- Níbo ni Bó̩lá ti n s̩is̩é̩? (a) ò̩là (b) àpà (c) Sò̩be̩ (d)abraka.
- Ta ni lóyà? (a) Bó̩lá (b) Dáramájà (c) Tìjání (d) Ló̩ládé.
- Fe̩nu kò túmò̩ sí———–(a) pinnu (b) dábàá (c) sàníyàn (d) gbèrò.
- Ta ló dàgbà jù? (a) Bó̩lá (b) Rè̩mí (c) Dáramájà (d) Tìjání.
- Ìlú ò̩là ni———– (a) O̩láolú bímo̩ sí (b) Dáramájà tí n s̩is̩é̩ (c) Rè̩mí tí n kàwé (d) ilé-ìwòsàn ìjo̩ba.
- Àko̩lé tí ó bá àyo̩kà yìí mu jù ní—–(a) àwè̩je̩-mè̩mu (b) èrè tító̩ o̩mo̩ (c) o̩jó ìbí (d) ilú ò̩là.
Owó s̩e pàtàkì, ó s̩e kókó. Bí ó tilè̩ jé̩ pé owó kò fé̩ kí e̩niké̩ni dámò̩ràn Kankan lé̩yìn òun, síbè̩ a gbo̩dò̩ mò̩ pé ìr’ans̩é̩ ló jé̩. Kò yé̩ kí ó di ò̩gá fún e̩niké̩ni tí o̩ba òkè bá fi s̩e búrùjí fún. Láyé àtijó̩, bí e̩nikan bá s̩is̩é̩ tó lówó láàárín e̩bí, gbogbo e̩bí lápapò̩ ni yóò jànfààní rè̩. Ìmò̩ wo̩n nípa owó pé kò niran, kò jé̩ kí wó̩n di agbéraga. Bí àwo̩n bàbá wa tin i ìtara is̩é̩ ajé tó, wo̩n kì í sábà gbò̩nà àlùmò̩kó̩ró̩í wá owó. Lode òní, àwo̩n ènìyàn n digunjalè, wó̩n n s̩é̩s̩ó, wó̩n n gbó̩mo̩, wó̩n sì n gbé kokeènì láti lówó.
- Àyo̩kà yìí fihàn pé owó jé̩——–(a) agbéraga (b) ò̩gá (c) ìráns̩é̩ (d) onítara.
- Ò̩nà wo ló dára jù l’ati lówó? (a) os̩ó s̩ís̩é̩ (b) o̩mo̩ gbígbé (c) is̩é̩ s̩ís̩e (d) gbígbó̩ té̩bí.
- Àkó̩lé tí ó bá àyo̩kà yìí mú jù ni —— (a) àwo̩n adigunjalè (b) owó níní (c) ànfààní olówó (d) gbígbé kokéènì.
ÀRÒKÒ̩/LÉ̩TÀ
- Irúfé̩ àròko̩ won i is̩é̩ ni òògùn ìs̩é̩ je̩ mó̩ jù? (a) aje̩mó̩-ìs̩ípayá (b) ìsò̩rò̩ngbèsì (c) as̩àpèjúwe (d) asò̩tàn.
- Èwo ní ó jè̩ mó̩ àròko̩ aje̩mó̩-ìs̩ípayá jù? (a) is̩é̩ déré̩bà dára ju is̩é̩ káfíntà lo̩ (b) ilé ìgbè̩bí àdúgbò mí (c) ìwà o̩mo̩lúàbí (d) eré orí ìtàgé kan ti mow ò.
- Èwo ni orí-ò̩rò̩ tí ó je̩ mó̩ àròko̩ asò̩tàn jù? (a) abé̩ré àje̩sára (b) o̩wó̩ o̩mo̩dé ò tó pe̩pe̩ (c) ìrìn àjò kan tí mo lo̩ lójú omi (d) dídé̩kun ìwà ìbàjé̩ ní àwo̩n ilé ìwé wa.
- Lé̩tà gbè̩fè̩ ni lé̩tà sí——- (a) ìyàwó àfé̩só̩nà (b) ilé is̩é̩ àdáni (c) Gómínà ìpínlè̩ (d) àjo̩ èrò ìrìnnà.
ÈTÒ ÌRÓ
- [N] Jé̩——— (a) afúnupè (b) aréhó̩n (c) às̩éès̩étán (d) asé̩nupè.
- Àfàsé àti è̩yìn-ahó̩n ni a fi pe——-(a) [j] (b) [s] (c) [k] (d)[b].
- Fáwèlì ayanupè ni——– (a) [e] (b) [u] (c) [o] (d) [a].
- Àròjinlè̩ jé̩ ò̩rò̩ oní sílébù——–(a) méjì (b) mé̩ta (c) mé̩rin (d) márùn-ún.
- Àrànmé̩yìn jé̩yo̩ nínú——– (a) ojàaba (b) àléèbá (c)aróoko (d) ewéená.
- Èwo ni ó tò̩nà? (a) olóótó̩ (b) olóòótó̩ (c) olóóótó̩ (d) olóòtó̩.
GÍRÁMÀ
- iy̩o̩ diè̩ ni mò f́e̩ ‘d́iè̩’ j́e̩—— (a) ò̩rò̩ ìs̩e (b) ò̩rò̩ oŕuko̩ (c) ò̩rò̩-at́okùn (d) ò̩rò̩-àpèj́uwe.
- Èwo ni ò̩rò̩ ìs̩e ńińu Ad́e ŕant́I ò̩rò̩ àjo̩so̩ wa? (a) wa (b) àjo̩so̩ (c) Ad́e (d) ŕant́i.
- Aẃe̩-gb́oĺohùn as̩àpèj́uwe je̩yo̩ ńińu——(a) ḱa ńI ́o ẃa, n b́a ḱi i (b) ‘ mà́a ḱo̩ iĺe ḱI n t́o ra ḿo̩tò’ (c) ‘ ́o f́e̩ ìyàẃo t́I ́o re̩wà’ (d)’ o̩mo̩ ńaà ẃu b́I b́uŕe̩di s̩e n ẃu’.
- Èwo ni gb́oĺohùn aĺakànpò̩? (a) iĺe iś̩e̩ ńaà ti j́o ṕat́aṕat́a (b) bàb́a je̩un ́o sì ýo (c) è̩wù t́I bàb́a wò̩ funfun (d) Àìńa ni ́o mu gaàri.
- Ò̩rò̩-aŕo̩pò̩-afaraj́oŕuko̩ ni ———-(a) èmi (b) wa (c) wo̩n (d) ýin.
- ——— ni oŕI f́un àṕolà-at́o̩kùn (a) ò̩rò̩-oŕuko̩ (b) ò̩rò̩-ìs̩e (c) ‘ò̩rò̩-at́o̩kùn (d) ò̩rò̩-è̩ýan.
ÌTUMÒ̩ ÈDÈ
- My journey to the beach was successful (a) mo paŕI ìrìn àjò mi śI et́ikun (b) ìrìn àjò mi si et́ikun yo̩ŕI śI rere (c)ìrìn àjò mi ńI et́ikun yo̩ŕI śI rere (d) mo paŕI ìrìn àjò mi śI et́ikun.
- Half a loaf is better than none. (a) ààbò̩ b́uŕe̩dì sàn ju òfo lo̩ (b) ́o d́ara b́uŕe̩dì wà ĺáabò̩ jù odindi ĺo̩ (c) ààbò̩ ýa ju aĺaìŕI ŕaŕa (d) ohun t́o so̩nù ni à n ẃa kiri.
- The labour union appealed to workers to be patient. (a) àjo̩ òs̩ìś̩e̩ pàro̩wà f́un àwo̩n òs̩ìś̩e̩ ĺati ńI sù́urù (b) ajò̩ òsìs̩è̩ f́e̩ ḱI àwo̩n òs̩ìś̩e̩ śo̩ra gidigidi (c) àjo̩ òs̩ìś̩e̩ kò faramo̩ àìńI sù́urù àwo̩n òs̩ìś̩e̩ (d) àjo̩ òs̩ìś̩e̩ be̩ àwo̩n òs̩ìś̩e̩ ĺati gba ḱaḿu.
- It is nice to see you again. (a) ́o d́ara t́I mo ŕI o̩ (b) ́o d́ara t́I a t́un ŕI ara wa (c) o d́ara ḱI a ŕira (d) ́o dara ḱI a lè ḿaa ŕira wa.
ÌṔIN B-ĹIT́IŔES̩Ò̩
- Ànḱasiìfù ýin ti s̩ub́u. ò̩rò̩ t́I ́o ye̩ ḱI a fi d́ipò ‘s̩ub́u’ ni ——-(a)pò́oŕa (b) dò̩t́I (c) wo̩ĺe (d) j́ab́o̩.
- Ò̩bo̩ n gb́o̩bo̩ gò̩pe̩ j́e̩ àpe̩e̩re̩ ò̩rò̩—– (a) aḱo̩niĺe̩nu (b) àgb́o̩ugb́anù (c) àgb́o̩ŕe̩rìn-́in (d) àḿus̩agb́ara.
- Èwo ni òwe? (a) e̩ ḱu o̩ẃo̩ ĺomi (b) iś̩e̩ ni òògùn ìś̩e̩ (c) ḿa gbàgb́e iĺe (d) olè f́e̩ raso̩.
- Ḿo fe̩ lo̩ d́aẃo̩ te̩lè̩ j́e̩ àpe̩e̩re̩——– (a) àdàpè (b) àẃitunẃI (c) àfid́ipò (d) aso̩reǵ́eè.
ÀĹO̩ ÀPAGBÈ: ÒPÒ̩ĹO ÀTI ÈRÒ O̩KO̩ OŔI OMI
- Ibo ni ò̩pò̩ĺo̩ ḿaa n gb́e? (a) ińu ìkòkò àmù (b) ińu omi tàb́I ibi t́o b́a tutu (c) ińu ihò ńińu igb́o (d) ińu òḱuta.
- Iru è́eb́u wo ni ẃo̩n b́u ò̩pò̩ĺo̩? (a) oĺoj́u rogodo (b) e̩ĺe̩nu nĺa (c) oĺori nĺa (d) aĺara ṕeipè̩i.
- Ḱin ni ò̩pò̩ĺo̩ ḱo̩ḱo̩ s̩e f́un àwo̩n èrò ińu o̩kò̩ lati fihàn ṕe è́eb́u yìi dun òun? (a) ́́o dà ẃo̩n śomi ĺe̩è̩kkan ńaà (b)́o yo̩ ẃo̩n śomi ĺe̩yo̩ kò̩ò̩kan (c) ́o doj́u o̩kò̩ d́e (d) ́o ḱo̩ḱo̩ dà ẃo̩n śilè̩.
- Ḱin ni ́o s̩e̩lè̩ śI o̩kò̩ ńigbà t́I ò̩pò̩lo̩ n d́a tu e̩ni t́o b́u u lo̩? (a) o̩kò̩ dój́ud́e (b) o̩kò̩ rì śisàlè̩ omi (c) o̩kò̩ là śI ḿejì (d) o̩kò̩ d́uŕo śoj́ukan.
- ———- ni ́o gbè̩yìn e̩ni t́o b́u Ìjàṕa. (a) odò gb́e e lo̩ (b) ́o pokùnso (c) ́o wè̩ gòkè f́unra è̩ (d) ́o di e̩ŕu ò̩pò̩ĺo̩.
EWÌ: ÀWO̩N OŔIKÌ OŔILÈ̩ ḾE̩TÀD́INĹO̩GBÒ̩N.
- Ń́ińu oŕikì “ oŕilè̩ E̩ĺe̩rìn ni ÈRÌNMÒJ́E̩ àwo̩n ———- làwo̩n o̩mo̩ ò́j́e yì́I (a) ḿe̩rin (b) ḿe̩ta (c) ḿejì (d) ḿeje.
- Ńińu oŕikì ‘ìran òṕoḿuĺeŕo’ ḱI ni ẃo̩n ḿaa n je̩ ńińu o̩bè̩? (a) òŕI (b) àd́in àgbo̩n (c) epo pupa (d) ýankò.
- Ìran wo ni ẃo̩n n ki ni ‘oj́u ŕabe̩ śa’ (a) òṕoḿuĺeŕo (b) oĺuf́e̩ (c) oĺu-ò̩́j́e̩ (d) arè̩sà.
- E̩ye̩ è̩gà j́e̩ èèwò ́fun ìran (a) oĺuf́e̩ (b)eĺe̩rin (c) oĺu-ò̩jè̩ (d)arè̩śa.
- Às̩à àwo̩n ìlàŕI Oĺufè̩ ni ṕe ẃo̩n ḿaa n (a) f́ari aṕa kan (b) gbin òẃu (c) śa ĺój́u ogun (d) sùn ńińu iĺe imò.
ÌṔIN D-ÀS̩À.
- Ibo ni oŕuko̩ t́I a ́o so̩ o̩mo̩ e̩ni ḿaa n gb́e ĺara? (a) oŕI (b) o̩ẃo̩ (c)ińu (d) e̩ńu.
- Ńinu às̩à wo ni adìye̩ ìrànà ti ẃulò? (a) ìsìnḱu (b)ìẃuye (c) ìgb́eyàwò (d)ìso̩mo̩ĺoŕuko̩.
- Ò̩t́un we̩ òs̩ì òs̩ì we̩ ò̩t́un, ĺo̩ẃo̩ f́I ́I ḿo̩ je̩ ḿo̩ às̩à—— (a) ìbò̩wò̩-fagbà (b) ìranra-e̩ni-ĺo̩ẃo̩ (c) oyè jíj́e̩ (d)oǵun ṕinṕin.
- È̩yà j́e̩ irin iś̩e̩——- (a) àgbè̩de̩ (b) o̩de̩ (c)ad́e̩mu (d)aĺaŕo.
- Èwo ni a ḿaa n ĺe śoj́́u? (a) osùn (b) là́alì (c) tìŕoò (d) àt́ikè.
- O̩mo̩ t́o b́a mo̩ẃo̩ ́I wè̩ ́a b́agbà je̩un je̩ ḿo̩ às̩à—- (a) ìranra-e̩ni-ĺo̩ẃo̩ (b)ìḱomó̩j́ade (c)ìbò̩wò̩-f́agbà (d) ìfo̩ẃo̩-soẃo̩-pò̩.
ṔEPÀ 2
D́ahùn ìb́eèrè ḿe̩fà ĺapapò̩: ḿe̩ta ĺati ìṕin A, ḿejì ĺati ìṕin B àti ò̩kan ĺati ìṕin D.
ÌṔIN A-ÈDÈ
D́́ahùn ìb́eèrè ḿe̩ta ṕeŕe ńińu ìṕin yì́i.
- Ko̩ àròko̩ ti kò d́in ńI 350 e̩yo̩ ò̩rò̩ ĺoŕI oŕI ò̩rò̩ kan s̩os̩o ti o b́a yàn.
- Ìd́ije íj́o kan t́I ́o ẃaýe ńI iĺe ìẃe re̩
- Akitiyan àjo̩ è̩ś̩o̩ oj́u-ò̩nà
- Oge ś̩is̩e
- Oẃo ni a fi n saýe
- Ko̩ ĺe̩tà si ò̩ŕe̩ re̩ ĺati gbà ́a ńiyàńj́u ńipa àwo̩n nnkan t́I ́o gbo̩dò̩ s̩e ĺati gb́aradì f́un ìd́anwò às̩eḱagb́a t́I ́o n bò̩ yì́i.
ÈTÒ ÌŔO
Dahùn ìb́eèrè kan s̩os̩o ńihìn-́in
- (a) fi f́awè̩lì àìŕanḿupè èdè Yorùb́a hàn ĺoŕI àte̩ f́awè̩lì.
(b) lo ò̩kò̩ò̩kan f́awè̩lì t́I ́o je̩yo̩ ĺoŕI àte̩ ńaà ńińu ò̩rò̩ ońisiĺebù me̩ta-ḿe̩ta.
- (a) ko̩ àpe̩e̩re̩ ḿejì-ḿejì f́un ò̩kò̩ò̩kan ìsò̩ŕI ḱo̩nśonàntì wò̩nýi:
- Afèrìgìpè (ii) afàfàsèfètè pè (iii) àìkùnyùn (iv) àkùnyùn.
(b) fi m’eje ńińu àwo̩n ḱo̩nśonàntì t́I o ko̩ ni 3(a) hàn ńinu ò̩rò̩ ḿee ò̩tò̩ò̩tò̩( fi àmì ohùn śI ori àwo̩n àpe̩e̩re̩ re̩).
GRÁMÀ
Dáhùn ibèèrè kan s̩os̩o nihin-in
- (a) Ko̩ àpe̩e̩re̩ kò̩ò̩kan fún àwo̩n è̩yà ò̩rò̩ is̩e wò̩nyi ki ó si lò ó ninú gbólóhùn: (1)as̩èbéèrè (ii) alápèpadà (iii) as̩èróyin (iv) àsinpò̩ (v)as̩òkùnfà.
(b) Lo àwo̩n ò̩rò̩ wò̩nyi gé̩gé̩ bi olùwà tàbi àbò̩ ninú gbólóhùn: (i) ikú (ii) itura (iii) àdúrà (iv) o̩gbó̩n (v)àánú.
- Ye̩ `awo̩n gbólóhùn wò̩nyi wò ki o si dáhùn àwo̩n ibéèrè ti ó tè̩lé wo̩n: (i)O lo̩ (ii) Gbogbo wa ni a ri I (iii) Wó̩n ti s̩etán (iv) Tis̩à máa n gba iwé yin (v) N ó s̩e bi o ti wi
(a) s̩e àpèjúwe àwo̩n ò̩rò̩ ti a fàlà si nidii.
(b) So̩ ò̩kò̩ò̩kan gbólóhùn náà di gbólóhùn àyisódi.
IPiN B:LiTiRÉS̩Ò̩:
D́́ahùn ìb́eèrè ḿe̩ji ṕeŕe ńińu ìṕin yì́i.
Itàn àròs̩o̩:àkójo̩pò̩ àló̩-ìjàpá.
- Ninú `aló̩”ijàpá àti ìyá è̩lé̩pà” sàlàyé ohun ti ó fà á ti ò̩sanyin e̩lé̩sè̩ kan mú ijàpá lo̩ si ilé O̩ba.
Àwo̩n oriki orilè̩ mé̩tàdinlógbò̩n.
- Ninú oriki iran Àágberi” sàlàyé bi Àágberi s̩e di o̩mo̩ e̩kùn ayé.
ERÉ- ONiSE:ègè dídá
- Ki ni pàtàki tàbi iwúlò ègè dídá?
LiTiRÉS̩Ò̩ ÀPiLÈ̩KO̩
Dáhùn ibèèrè kan s̩os̩o nihin-in:
Mó̩remí àjàsorò.
- Sàlàyé lóri onirúurú às̩à ilè̩ Yorùbá ti ó je̩yo̩ ninú rè̩.
Ewi: ò̩rò̩ e̩nu akéwì:
- Sàlàyé lé̩kùnré̩ré̩ kókó ti akéwi mé̩nubà lóri pè̩gànpè̩gàn.
Eré-onitàn : nítorí owó
- È̩kó̩ wo gan-an ni ònkò̩wé yii fi itàn inú iwé rè̩ kó̩?
IPiN D: ÀS̩À
- Sò̩rò̩ lóri ò̩nà ti à n gbà yá owó ni ilè̩ Yorùbá.
- Sàlàyé tókún lóri àkúdàáyà àti as̩è̩yinwáyé.